kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

hibeekay – anu كلمات اغاني

Loading...

lead: baba sanu mi
ranmilowo oluwa
jeki orun si fun mi
kanu soro laye mi

all: baba sanu mi
ranmilowo oluwa
jeki orun si fun mi
kanu soro laye mi

lead: baba sanu mi
ranmilowo oluwa
jeki orun si fun mi
kanu soro laye mi
all: baba sanu mi
ranmilowo oluwa
jeki orun si fun mi
kanu soro laye mi

lead: kosi ohun ti mo le se
lai si iranlowo re baba
ayeraye ma wo mi niran jowo dasi oro aye mi
ki anu re fohun ki gbogbo idawole mi ma yori si rere
bi orun ba si fun mi
ase irorun ohun lo ma tele
adura a ma gba alubarika a wole ise a mu ere wa
ire lotun ire losi laye eyan orin ope a tun yo

all: baba sanu mi
ranmilowo oluwa
jeki orun si fun mi
kanu soro laye mi

lead: oro re fi yewa, iwo yio sanu fun eniti iwo o sanu fun
eyonu re yio wa lori eniti iwo ba yonu si laye ati ni orun
baba jowo je n nipin ninu eyonu re
kin se nipa adura, abi iwa mimo abi eto bikose nipa ore ofe ati orire
aye mi nilo ore ofe ati orire lati odo re baba mi
kanu re joba laye mi ati ohun gbogbo to jemo temi
chorus: baba sanu mi
ranmilowo oluwa
jeki orun si fun mi
kanu soro laye mi

lead: silekun ayo mi
baba silekun ayo mi
ibanuje o, jeko jina silemi
wa mu inu mi dun, baba onile ayo
oro ayo mi, ma jeko pamilekun

all: silekun ayo mi
baba silekun ayo mi
ibanuje o, jeko jina silemi
wa mu inu mi dun, baba onile ayo
oro ayo mi, ma jeko pamilekun

silekun ayo mi
baba silekun ayo mi
ibanuje o, jeko jina silemi
wa mu inu mi dun, baba onile ayo
oro ayo mi, ma jeko pamilekun

all: baba sanu mi
ranmilowo oluwa
jeki orun si fun mi
kanu soro laye mi
(till fade)

كلمات أغنية عشوائية

اهم الاغاني لهذا الاسبوع

Loading...