congress musicfactory – mímó ni òdó àgùtan كلمات اغاني
mímó ni òdó àgùtan
[akorin}
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[ẹsẹ 1]
gbogbo eda f’ogo fun o
gbogbo okan wa bukun f’oruko re
ede, eya ati awon orile ede
eniyan mimo nkorin iyin re
[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[ẹsẹ 2]
a teriba nibi mimo re
a gbowo s’oke a juba re
oluwa eyin nikan l’owo yi ye
iwo nikan ni gbogbo iyin ye
gbogbo iyin
[akorin]
mimo, mimo
mimo l’odo agutan
oluwa alagbara
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o tun nbo wa
[ipari]
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa t’o nbe
ti o si wa to tun nbo waaaa
كلمات أغنية عشوائية
- 257ers › 257ers – drei rosa schleifchen كلمات اغاني
- les freres lumieres › les frères lumières – de l’ombre à la lumière كلمات اغاني
- alter bridge › alter bridge – dying light كلمات اغاني
- the californicators › the californicators – californication كلمات اغاني
- neil diamond › neil diamond – what’s it gonna be كلمات اغاني
- twiztid › twiztid – drugs & alcohol ft. blaze ya dead homie and dom كلمات اغاني
- dr awkward › dr. awkward – alchemy كلمات اغاني
- mina › mina – johnny kiss كلمات اغاني
- atmosphere › atmosphere – we ain’t gonna die today كلمات اغاني
- t pharaohll › t. pharaohll – the fight for flight كلمات اغاني