zlatan - compulsory course كلمات الأغنية
[intro]
ibile!
hayi!
thou shall not carry over
any course
one unit course
two units course
four units course
ibile! ibile!! wo!
[pre_chorus]
aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!)
mo fe se yin ni anfani
e te ti ke ti e gbo offer mi
aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!)
mo fe se yin ni anfani
e te ti ke ti e gbo offer mi
hayi! hayi!! wo!
[chorus]
compulsory course ni ise yin
compulsory course ni ise yin
compulsory course ni ise yin
ko olorun ma je n carry ise yin
compulsory course ni ise yin
compulsory course ni ise yin
compulsory course ni ise yin
ko olorun ma je n carry ise yin
ahn! wo!
[verse 1]
lalakukulala
iwa buruku ba e dagba
iwo ni vixen
iwo ni dancer
mogbo pe o n jijo
you’re so bad like that
high like that
kekere lo ti ja by far
ise woli ise alfa
mogbo pe on gbawe adura a gba (ha!)
sister veronica
e n je ise laphorita
home and away le tun ta
(ha) market yin ta
eje mon lo ko kin se omi
won ni four rounds ko kin yo yin o
won ti cast ladugbo yin o
ibile! ladugbo yin oo
foto foto (foto foto)
o para para (e para pare)
e dara dara…..bi omi o
hayi! ibile! ibile!!
eje mon lo ko kin se omi
won ni four rounds ko kin yo yin o
won ti cast ladugbo yin o
hayi! ladugbo yin oo
je o mo!
[pre_chorus]
aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!)
mo fe se yin ni anfani
e te ti ke ti e gbo offer mi hayi!
aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!)
mo fe se yin ni anfani
e te ti ke ti e gbo offer mi
hayi! hayi!! wo!
[chorus]
compulsory course ni ise yin (mathematics)
compulsory course ni ise yin (physics)
compulsory course ni ise yin
ko olorun ma je n carry ise yin
compulsory course ni ise yin
compulsory course ni ise yin
compulsory course ni ise yin
ko olorun ma je n carry ise yin
hayi
[verse 2]
oro padi o se salaye
bi adiye se mo fe saba le
e lo mo ma san ti n ba gbara le
ti ma fi pillow le se ti n ba le
o sa ri bo se mo lololo
omu ti lo omo ma se fun owo
ki se a se dagba a se darugbo
eyi to ba se le lomo ma ko
ahn!
sister veronica
e n je ise laphorita
home and away le tun ta
(ha) market yin ta
eje mon lo ko kin se omi
won ni four rounds ko kin yo yin o
won ti cast ladugbo yin o
ibile! ladugbo yin oo
foto foto (foto foto)
o para para (e para pare)
e dara dara…..bi omi o
hayi! ibile! ibile!!
eje mon lo ko kin se omi
won ni four rounds ko kin yo yin o
won ti cast ladugbo yin o
hayi! ladugbo yin oo
je o mo!
[pre_chorus]
aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!)
mo fe se yin ni anfani
e te ti ke ti e gbo offer mi hayi!
aunty aunty a ba yin soro e n yari (ha!)
mo fe se yin ni anfani
e te ti ke ti e gbo offer mi
hayi! hayi!! wo!
[chorus]
compulsory course ni ise yin (mathematics)
compulsory course ni ise yin (physics)
compulsory course ni ise yin
ko olorun ma je n carry ise yin
compulsory course ni ise yin
compulsory course ni ise yin
compulsory course ni ise yin
ko olorun ma je n carry ise yin
[outro]
ha! ha!!
kaka lo tobi to bayi
ibebe lo tobi to bayi ha!
kaka lo tobi to bayi
ibebe lo buru to bayi
kaka lo tobi to bayi
compulsory course ni ise yi
mathematics ma teti le o ise yin
wa love me to ba je idi ni mathematics
كلمات أغنية عشوائية
- 曹雅雯 - 感謝 كلمات الأغنية
- joy denalane - rotschwarz كلمات الأغنية
- loreno mayer feat. nickobella & alius - home كلمات الأغنية
- roch voisine - dieux verts كلمات الأغنية
- victoria vargas - dia de milagro كلمات الأغنية
- rafa pabon - sin ti كلمات الأغنية
- elias matos - cuenta conmigo كلمات الأغنية
- sikander kahlon - 2018 flow كلمات الأغنية
- breakerz - great ambitious كلمات الأغنية
- элизиум - джаджаил كلمات الأغنية