kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

ynl sam - o ti se كلمات الأغنية

Loading...

{intro}
o ti se
baba ti se
o ti se
baba ti se o o

{verse 1}
mo feran re jesu mi
mo feran re baba mi
ese
e ma se o
ire te se fun mi
o po
ó pòjù láti ro tori
melo ni emi a ro
melo ni emi a ka
melo ni emi a so
ninu ire te se fun mi
baba e se

{pre_chorus}
o ti se o
baba ti se o
ohun ti o nba mi leru
baba ti se o
{chorus}
emi a jo
emi a yo
oun to n ba mi leru
baba ti she
emi a jo
emi a yo
oun to n ba mi leru
baba ti se

emi a jo
emi a yo
oun to n ba mi leru
baba ti she
emi a jo
emi a yo
oun to n ba mi leru
baba ti se

{bridge}
o ti se
baba ti se
o ti se
baba ti se o o

o ti se
baba ti sе
o ti se
baba ti se o o
{versе 2}
won ro mi phin
pe ko leda mo
sugbon jesu o gbagbe mi
baba ese
eyin ni aabo mi
eyin ni asà mi
oba nla mo wa dupe
mo subu
baba gbe mi soke
mo ja bo
baba gbe mi dide

{pre_chorus}
o ti se o
baba ti se o
ohun ti o nba mi leru
baba ti se o

{chorus}
emi a jo
emi a yo
ohun ti o nba mi leru
baba ti se
emi a jo
emi a yo
ohun ti o nba mi leru
baba ti se
emi a jo
emi a yo
ohun ti o nba mi leru
baba ti se
emi a jo
emi a yo
ohun ti o nba mi leru
baba ti se

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغاني الشهيرة

Loading...