kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

tony maria - jesu n gbo adura كلمات الأغنية

Loading...

jesu yi n gbo adura mi o, o n gbo
oba ogo n gbo adura mi o, o n gbo
oro oluwa ko ni lo laise

oro oluwa ko ni lo laise

beere, a o fi fun o
wa kiri, eyin o si ri
kan ′kun, a o si si le fun yin
baba lo le se ohun gbogbo
mo wa, lati dupe o
ope, atokan wa
jowo je ki, ope mi d’odo re
ki erin mi le po, jaburata
baba lo le se ohun gbogbo

jesu yi n gbo adura mi o, o n gbo
oba ogo n gbo adura mi o, o n gbo
oro oluwa ko ni lo laise
oro oluwa ko ni lo laise

oba to ji lasaru dide
o gbo ti hanna
o gbo ti jabezi
o gbo ti namani
o wo obinrin, onisu eje san
o wo awon, adete san
baba lo le se ohun gbogbo
ekun, oko faraho
eleti, gbohun gbaroye
o so oloriburuku, d′olorire
o wo okan, oni rele san
baba lo le se ohun gbogbo

jesu yi n gbo adura mi o, o n gbo
oba ogo n gbo adura mi o, o n gbo
oro oluwa ko ni lo laise
oro oluwa ko ni lo laise

oro baba mi yo se titi aye o
oro oluwa ko ni lo lai se
o gbe oro re ga ju oruko re lo
oro oluwa ko ni lo lai se
ni pa oro lo fi da ile aye o
oro oluwa ko ni lo la se
egungun gbigbe o da alaye o
oro oluwa ko ni lo laisee

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغاني الشهيرة

Loading...