kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

temitope serentainer - jesu awa yio sin o (ccc hymn 62) كلمات أغنية

Loading...

jesu
àwa yíò sìn ọ′
jesu
àwa yíò sìn ọ’
n′íbi mímọ’ yìí
l’áàrin ìjọ nlá rẹ
àwa yíò sìn ọ′
títí d′ópin
àwa yíò mú ‘bùkún re′lé
jesu
àwa yíò sìn ọ’
jesu
àwa yíò sìn ọ′
n’íbi mímọ′ yìí
l’áàrin ìjọ nlá rẹ
èmi ó sìn ọ’
títí d′ópin
èmi ó mú ′bùkún re’lé
jesu
àwa yíò sìn ọ′
jesu
àwa yíò sìn ọ’
n′íbi mímọ’ yìí
l′áàrin ìjọ nlá rẹ
àwa yíò sìn ọ’
títí d’ópin
àwa yíò mú ′bùkún re′lé
àmín

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغنية الشائعة حالياً

Loading...