
sheedey b - oko meji كلمات أغنية
as a baby girl for life
mo fẹ lọkọ meji
tomi ati bolu
mo fẹ lọkọ meji
tomi ati bolu
tomiwa ni fẹ mi
oun dun mọ mi
bolu ni fẹ mi, ó pọ púpọ
hun fẹ fi kan lẹ́ fún kan o
hun lẹ lọkọ meji ni
mo fẹ lọkọ meji
’cause i be baby girl for life
(baby girl for life)
mo fẹ lọkọ meji
’cause i be baby girl for life
tomi a ma wa mi wá’le
he dey come to the jungle to rescue
and we dey play ten_te
with expression toh bad
sweetie mouth
ayọ ju wa lálẹ wá wò mí
àmọ́ tomi ò le fún mi lọ́wọ́
tomi ò le rà aṣọ fún mi
tí n ba tẹ̀wọ̀ pé àní kò s’ọwọ́
tomi no getti money to spend
kò ní rà ẹjẹ dindin wá
bó bá dàlẹ́
ṣùgbọ́n bolu dey spend me
the money
carat gold
odogwu ò tẹ̀wọ̀
owó dùn mọ mi
ìkẹ̀ dùn mọ mi
owó dùn mọ mi
ìkẹ̀ dùn mọ mi
ṣe ìkẹ̀ ni kí n mú ni à?
àbí kí n mú owó?
mo fẹ lọkọ meji
tomi ati bolu
mo fẹ lọkọ meji
tomi ati bolu
tomiwa ni fẹ mi
oun dun mọ mi
bolu ni fẹ mi, ó pọ púpọ
hun fẹ fi kan lẹ́ fún kan o
hun lẹ lọkọ meji ni
mo fẹ lọkọ meji
’cause i be baby girl for life
(baby girl for life)
mo fẹ lọkọ meji
’cause i be baby girl for life
tomi a ma ba mi fo aṣọ
aṣọ tí bolu bá ra fún mi
but i think i know what i
(want, want, want, want, want, want, want, want)
ẹnu ẹ pau pau pau
hold your advice
keep your advice
advise osi o
advise iya
àbí ṣe na love i go chop?
spend me the money
spoil me with money
tomi ti jẹ gbèsè
bolu gan gan gan l’oga
yé ma lọkọ meji
ojú kan gangan la dà ni
i’m a baby girl for life
can’t you see
i’m a baby girl for life
mo fẹ lọkọ meji
tomi ati bolu
mo fẹ lọkọ meji
tomi ati bolu
tomiwa ni fẹ mi
oun dun mọ mi
bolu ni fẹ mi, ó pọ púpọ
hun fẹ fi kan lẹ́ fún kan o
hun lẹ lọkọ meji ni
mo fẹ lọkọ meji
’cause i be baby girl for life
(baby girl for life)
mo fẹ lọkọ meji
’cause i be baby girl for life
(as a baby girl for life)
gimme the money
gimme the money
gimme the money
(bíkọ yé me go)
yé me go
yé me go
yé me go
(mi ò rá ye sume sume)
fún mi lọ́wọ́
fún mi lọ́wọ́
fún mi lọ́wọ́
(lemme smile more, lemme laugh more)
bá ni kùdì
bá ni kùdì
bá ni kùdì
as a baby girl for life
كلمات أغنية عشوائية
- christina milian - one kiss كلمات أغنية
- celine dion - do you hear what i hear? كلمات أغنية
- rudi myntevik - gud, vi ber كلمات أغنية
- rudi myntevik - himmelen كلمات أغنية
- rugrats - all grown up كلمات أغنية
- the watermen - roots girl كلمات أغنية
- the watermen - wired كلمات أغنية
- the watermen - dabbawala كلمات أغنية
- t i - swing your rag (louis rag) كلمات أغنية
- john mellencamp - i saw mommy kissing santa claus كلمات أغنية