
oriki - exu lyrics
[intro]
o sọ òkò l’ona o pá eiye l’oni
obá nilè kétu, láàróyè
[verse 1]
èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
láàróyè èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
èṣù awo
èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
láàróyè èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
èṣù awo
èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
láàróyè èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
èṣù awo
èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
láàróyè èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
èṣù awo
èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
láàróyè èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
èṣù awo
èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
láàróyè èṣù wa jú wò mọ̀n mọ̀n ki wò ọdára
èṣù awo
[verse 2]
ọdára ló ṣòro, ọdára ló ṣòro lọ́ọ̀nọ̀n
ọdára ló ṣòro e ló ṣòro ọdára ló ṣòro lọ́ọ̀nọ̀n
ọdára ló ṣòro, ọdára ló ṣòro lọ́ọ̀nọ̀n
ọdára ló ṣòro e ló ṣòro ọdára ló ṣòro lọ́ọ̀nọ̀n
ọdára ló ṣòro, ọdára ló ṣòro lọ́ọ̀nọ̀n
ọdára ló ṣòro e ló ṣòro ọdára ló ṣòro lọ́ọ̀nọ̀n
ọdára ló ṣòro, ọdára ló ṣòro lọ́ọ̀nọ̀n
ọdára ló ṣòro
[verse 3]
òjíṣẹ́ pa lé fún awo, ọdára pa lé sọ́ba
òjíṣẹ́ pa lé fún awo, ọdára pa lé sọ́ba
òjíṣẹ́ pa lé fún awo, ọdára pa lé sọ́ba
òjíṣẹ́ pa lé fún awo, ọdára pa lé sọ́ba
òjíṣẹ́ pa lé fún awo, ọdára pa lé sọ́ba
òjíṣẹ́ pa lé fún awo, ọdára pa lé sọ́ba
òjíṣẹ́ pa lé fún awo, ọdára pa lé sọ́ba
òjíṣẹ́ pa lé fún awo, ọdára pa lé sọ́ba
[verse 4]
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
alákétu rẹ̀ kétu bará, èṣù máa lọ́
Random Lyrics
- acdc - stormy may day lyrics
- acdc - the furor lyrics
- acdc - the honey roll lyrics
- acdc - the jack (full live version) lyrics
- acdc - the jack (live in paris) lyrics
- acdc - the jack (live) lyrics
- acdc - this house is on fire lyrics
- acdc - this means war lyrics
- acdc - touch too much (original) lyrics
- acdc - t.n.t. lyrics