oluwamillar - àlùbáríkà كلمات الأغنية
_àlùbáríkà._
ẹ jọ̀ọ́, àlùbáríkà l’èmí t’ọrọ
all that best rapping sh!t, keep am for your kọ̀rọ̀
àwọn olófo fẹ́ t’ẹnu ológo wá gb’ọ́rọ̀
wọ́n náá fé rí wèrè, mo wà ń lẹ̀, ìjọba horror
i sick die bí ẹní ní terminal illness
kò ń ṣ’òní, atí ń tìí lá t’aáye pátá kan àti packing shirt
mi ṣ’íwọ believing p’ón ṣì maa r’animal in there
ẹní á gbé ‘ná w’ojú ẹkùn ń sìyín ti l’ọ́rọ̀ tá fi wá bi ‘lẹ̀
e dey hot, ó ń gbá l’órí
wọ́n l’óóre n’igúnnugún ṣe tó pá l’órí
òun ló mú mi kálá dọ̀ dájú, mo ká ṣ’órí
ẹní yá ‘jú maa lá jú, torí ó dájú gọ̀mbọ́ á d’órí
i’m next up, á á better kẹ́ ẹ gbọ
henceforth, mií fẹ́ gbọ́ gbogbo best and rest talk
ẹ sọ f’àwọn biggest bruh tẹ́ ǹ hail, set up
ẹní ta féle fèle àf’ọ̀run ṣe next stop
sáré fún wọn ń send off, r’àrèmobọ̀ ehn, toor
wọ́n lẹ̀ ń ball? una worwor pass lukaku first touch
therefore, kí ló kan ayéfẹ́lẹ́ yín kan legwork
ẹ yé f’ikú w’óorun, sánmọ̀ ga ju earth lọ
ríró àrá ò ń ṣẹ gbẹ́ẹ dídún ká yìn ‘bọn
ẹ ẹ̀ tó gbangba sùn l’ọ́yẹ́, ìya yín ò man enough
2:34 làwọn ‘mo yín fẹ́ lọ rún mi mọ́ parking lot
miì ti hit, tán tí ń leak ju unreleased carti lọ
ẹ jọ̀ọ́, alubarika l’èmí t’ọrọ
all that best rapping sh!t, keep am for your kọ̀rọ̀
àwọn olófo fẹ́ t’ẹnu ológo wá gb’ọ́rọ̀
wọ́n náá fé rí wèrè, mo wà ń lẹ̀, ìjọba horror
mo ti sick, mo ti mad
wo kiní yìí, no be man
no be me, only jah
dúró di gbí, so me stand
tán bá wá, wọ́n maa lá, wọ́n maa já, wọ́n maa sá
wọ́n maa sáré kàbà kàbà kàbà
wón ń bẹ́, miì wá lè jágbе bàbá
ẹgbèrún ẹja ò tó b’odò l’ẹ́rù, ká yé fà ‘te matter
yíyọ́ kẹ́lẹ́ ẹkùn ò kí ń ṣe t’ojo
b’ẹ́ni еjò ti sán rí bá r’ékòló á sáré gbàgbe bàtà, tu ṣá
ẹ yé f’irun ‘mú pe moustache
àjànàkú ò ń ṣ’ẹranko tẹ maa bushwhack
èmi l’afẹ́fẹ́ tó b’ológì tí ò le sùn ń dark
so, ẹ move back, k’elélùbọ́ yín tó lo loseguard
ẹ gbàgbé pẹ maa r’áwa cancel
wọn ǹ kí ń unseat ẹni ọlọ́run fi j’alága council
àwá maa tá ‘kù
bí strike ò ṣe maa ń tire asuu
ni kòle r’àwa
bàbá, rapper yapa t’áwàá máá ń school
numero uno, them ku know if i dare dey two
a jẹ́ pé mo gbá right back, k’ọ́lọ́un máa jẹ́ n r’ésù
àwọn ‘mo tẹ́ ń lé ń sùn, dó mi wọ 10 de 2
but mi ò ń j’ètè, alayé, torí kiss náá fi shenk jesu
mo ti wí fún wọn tẹ́lẹ̀ kán ṣe pẹ̀lẹ́ẹ̀
pẹ̀lẹ́ pẹ̀lẹ́ dẹ̀ẹ́dẹ̀ẹ́ mìràwọ̀ yín, ehn brozay tẹ̀ẹ́ jẹ́
kẹ́lẹ́ kẹ́lẹ́, kẹ̀rẹ̀ kẹ̀rẹ̀, make you no come dey yẹ̀ gbẹ́ẹ̀
ko máa k’àgbákọ̀ kọ̀l’ẹ́rọ̀, boo re deeper boo re cele
àgbélèbú oníkálukú ṣọ̀tọ̀, all kinds
down to it, i no dey dull on top mine
ìyẹn ni pé i dey carry my cross one time
like alexander arnold tryna tee kane up, up nine
ó wúwo l’étí, tibí ńlá, e tóbi for mouth
ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ ò ń kún ágbọ̀n, agbára e no be for shout
jesu had 12 followers, if i dey follow am
this thing of mine, omo e no be for clout
motí ń bọ́ látìgbaa kanu dẹ́ ti ń goal ní portsmouth
kinda like wike, them no dey disown me for south
azul e no be small stout
ẹrukú dẹ̀ pọ̀ ọgá o
bi 25 car convoy ló ń tèlé gómìnà out
i never break, but i might break a heart, or maybe two or three
my louboutin na born again, ọmọ mi, it looks good on me
dior mi ò gbẹ́yìn, padi mi ó n’ígbàlà
zanotti l’ẹ́sẹ̀, wọn ‘mọ ń kígbe ìba yín bàbá
èmi n’idán tó máa mú wọn r’ìdánwò
a ṣẹ̀ ń m’ẹ́yẹ bọ̀ lápò ni, tasting leléyìí, ìtọ́wò
a gee, a gee f#ck up, a gee gon go like who go fill him diastema up, you know “èjí” gon go
ẹ jọ̀ọ́, àlùbáríkà l’èmí t’ọrọ
all that best rapping sh!t, keep am for your kọ̀rọ̀
àwọn olófo fẹ́ t’ẹnu ológo wá gb’ọ́rọ̀
wọ́n náá fé rí wèrè, mo wà ń lẹ̀, ìjọba horror
it’s done
كلمات أغنية عشوائية
- maikitol y el chusco - como a rata كلمات الأغنية
- psy feat. g-dragon - fact كلمات الأغنية
- sf9 - fanfare (japanese ver.) كلمات الأغنية
- cheezstereo - 순서에 상관없이 regardless of order كلمات الأغنية
- vallavan & kavya ajith - kadhalagi (duet) كلمات الأغنية
- timothy brindle - christ restores... (my identity, affections & image) كلمات الأغنية
- yamine - deadly كلمات الأغنية
- shooter starz - crusty crabs كلمات الأغنية
- jozyanne - coragem كلمات الأغنية
- jhene aiko - plz don't go كلمات الأغنية