kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

majur - oyá كلمات أغنية

Loading...

a kooro mì iná dé wà ayé
a kooro mì iná dé wa

a kooro mì iná dé wa, yánsàn
a kooro mì iná dé wa
bàgà
a kooro mì iná dé wa
bálè
a kooro mì iná dé wa
tọ́pẹ
a kooro mì iná dé wa
afẹ́fẹ
a kooro mì iná dé wa
àbọ̀mí
a kooro mì iná dé wa
ònìrà
a kooro mì iná dé wa
yánsàn
a kooro mì iná dé wa
pẹ̀tù
a kooro mì iná dé wa
afẹ́fẹ
a kooro mì iná dé wa
yánsàn
a kooro mì iná dé wa
ọya dé o, láriwo
ọya dé o, láriwo
ọya dé o, láriwo
ọya dé o, láriwo
ọya dé o, láriwo
ọya dé o, láriwo
ọya dé o, láriwo
ọya dé o, láriwo

ọya kooro ń lé, ó gerege
ọya kooro nlá, gààrà ga
obìnrin ṣọlá kooro n lé gerege
ọya kọ́ mọ rélọ

ọya kooro ń lé, ó gerege
ọya kooro nlá, gààrà ga
obìnrin ṣọlá kooro n lé gerege
ọya kọ́ mọ rélọ

ọya padà lóodò ọya, odò hó yà_yà
e l’ọya a padà lóodò ọya, odò hó yà_yà
ọya padà lóodò ọya, odò hó yà_yà
e l’ọya a padà lóodò ọya, odò hó yà_yà
ọya padà lóodò ọya, odò hó yà_yà
e l’ọya a padà lóodò ọya, odò hó yà_yà
ọya padà lóodò ọya, odò hó yà_yà
e l’ọya a padà lóodò ọya, odò hó yà_yà
ọya tètè, ọya tètè ayaba
ọya tètè, ọya
ọya tètè

ọya tètè, ọya
ọya tètè

ọya tètè, ọya
ọya tètè

ọya tètè, ọya
ọya tètè

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغنية الشائعة حالياً

Loading...