
king sunny adé - ja funmi كلمات أغنية
[chorus]
ori mi ye, jàá, ja fun mi
eda mi ye o, jàá, ja fun mi
ori mi ye, jàá, ja fun mi
eda mi ye o, jàá, ja fun mi
nítorí
ori agbe a ja fun agbe, ori àlùkò a ja fun o
ori agbe a ja fun agbe, ori àlùkò a ja fun o
eleda mi màá ma gbàgbé mi ye o
o ba ma ma ja o
[verse 1]
wọn do yi ka pa, apa o ka pa
wọn do yi ka pa, apa o ka pa
wọn do yi ko ṣe, apa o ko ṣe
wọn do yi ko ṣe, apa o ko ṣe
wọn do yi ka konga, ko ṣe binu ko si, oh
aiye, aiye
e be mo maa be aiye k’aiye ma ma ba waja
aso iyi ko ma faya mo wa lara
akye le o, ore mi aye ma le
aiye ti le aye toto, aiye aka kamura
atori laye to ba lo siwaju, a tún lu sẹ́yìn
atori laye je, to ba lo síwájú atun lu sẹ́yìn ni
[chorus]
ori mi ye, jàá, ja fun mi
eda mi ye o, jàá, ja fun mi
ori mi ye, jàá, ja fun mi
eda mi ye o, jàá, ja fun mi
nítorí
ori agbe a ja fun agbe, ori àlùkò a ja fun o
ori agbe a ja fun agbe, ori àlùkò a ja fun o
eleda mi màá ma gbàgbé mi yе o
o ba ma ma ja o
[verse 2]
ori eni lon gbe’re koni
orí wo ibi rеre gbe mi de
ese wo ibi rere gbe mi ya
orí wo ibi rere gbe mi de
ese wo ibi rere gbe mi ya si
tori onw_ngonloto
gonloto kowa
ow_ngoloto, goloto ngowa
[chorus]
orí mi ye, ja, ja, ja, ja fun mi
eda mi ye o, ja, ja, ja, ja fun mi
orí mi ye, jàá, ja fun mi
eda mi ye o, jàá, ja fun mi
nítorí
orí agbe a ja fun agbe, orí àlùkò a ja fun o
orí agbe a ja fun agbe, orí àlùkò a ja fun o
eleda mi màá ma gbàgbé mi ye o
o ba ma ma ja o
[verse 3]
bi koko ba pe ni leede
aki j’ori imado
bi a ba n jo ri imado yen
ajoku la o ma ni de
baba tun de ajo k_mo
iwon ara eni laamo
ai m’owon ara eni akoba lon kobani
tori, boti wu ki opolo tobi to
ile e lo mi a mo
boti wu ki opolo tobi to
ile e lo mi a mo
[chorus]
orí mi ye, jàá, ja fun mi
eda mi ye o, jàá, ja fun mi
orí bàbà mi, jàá, ja fun mi
orí màmá mi, jàá, ja fun mi
nítorí
orí agbe a ja fun agbe, orí àlùkò a ja fun o
orí agbe a ja fun agbe, orí àlùkò a ja fun o
eleda mi màá ma gbàgbé mi ye o
o ba ma ma ja o
كلمات أغنية عشوائية
- nights at toni's playhouse - the love letter by ardent lines كلمات أغنية
- separator - numb_days كلمات أغنية
- su lee - santa gimme sanity كلمات أغنية
- rilès - golden كلمات أغنية
- polarboiyeahz - gray aura كلمات أغنية
- madam macadam - olivia كلمات أغنية
- joyca - soulève moi كلمات أغنية
- sniff 'n' the tears - sometimes we find love كلمات أغنية
- jt hawk - hey كلمات أغنية
- $ir lt - growing كلمات أغنية