kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

congress musicfactory - wo olúwa كلمات الأغنية

Loading...

wo olúwa

[ẹsẹ 1]
(okunrin)
wo oluwa lori ite re
oba awon oba ati oluwa awon oluwa
ijoba re wa t-ti lailai
agbara ati ola nla re duro t-ti

(gbogbo wa)
wo o joba t-ti lailai
eni ologo t’awa feran
lati ainipekun ko yi pada
ti o ti wa ti o nbe to si nbo wa

[akorin}
a gbe yin ga
ko s’eni t’ale fi o we
a gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re
wo owo re
apapo eniyan mimo
a fi fun yin ni iyin giga

[ẹsẹ 2]
wo odo aguntan, omo olorun
oba to nsegun oba oun gbogbo
dun ipe re da araye lejo
j’ekamo pe oluwa alagbara njoba

[akorin}
a gbe yin ga
ko s’eni t’ale fi o we
a gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re
wo owo re
apapo eniyan mimo
a fi fun yin ni iyin giga

[akorin}
a gbe yin ga
ko s’eni t’ale fi o we
a gbe yin ga, bukun fun oruko mimo re
wo owo re
apapo eniyan mimo
a fi fun yin ni iyin giga
a fi fun yin ni iyin giga

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغاني الشهيرة

Loading...