kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

congress musicfactory - olórun wà níhîn (halleluya) كلمات الأغنية

Loading...

olórun wá nihín (halleluya)

[akorin]
halleluya!
halleluya!
halleluya!
oluwa olorun wa nihin

[akorin]
halleluya!
halleluya!
halleluya!
oluwa olorun wa nihin

[ẹsẹ 1]
e wa laarin eniyan yin
ogo re si nbuyo
fihan kakiri agbaye
ninu olanla re joba

[akorin]
halleluya!
halleluya!
halleluya!
oluwa olorun wa nihin

[akorin]
halleluya!
halleluya!
halleluya!
oluwa olorun wa nihin

[ẹsẹ 2]
pawa mo ka di mimo
mu wa rin gbogbo ona
dari wa s’ayeraye
t-ti lailai ao ma wi

[akorin]
halleluya!
halleluya!
halleluya!
oluwa olorun wa nihin

[akorin ipari]
halleluya!
halleluya!
halleluya!
oluwa olorun
oluwa olorun
oluwa olorun wa nihin

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغاني الشهيرة

Loading...