
chidinma - òsùbà كلمات أغنية
atógbára léé o……
ah ah ah ahahah
ah ah ah ahahah
ah ah ah ahahah
ìbèrù kò sí fún mi
ààyà ò fò mí o
aládé wúrà
olórun tó ga jù
olódodo
taló to ò
taló jú o lo báàmí
eni tó mo wà
oba tó mo wá
tó mo ohun gbogbo
osuba olórun ijáíyà
gbani gbani olórun ansáyà
eni tó lemìí mi
móò dé
osuba olórun ijáíyà
osuba olórun ijáíyà
gbani gbani olórun ansáyà
eni tó lemìí mi
móò dé
ooolódùmárè oo…..
oba’kódáayé oo……
ògbìgbàtíngbaaraiilara
asòròmayèohun oo……
ògbeninííjà
kéruobónijà
òpin òkun níí yà
ojí okú dìde
ìbàre mà rèé sir
eléburù ìké níì ó
eni tó mo wà
oba tó mo wà
tó mo ohun gbogbo
osuba olórun ijáíyà
osuba olórun ijáíyà
gbani gbani olórun ansáyà
eni tó lemìí mi
móò dé
osuba olórun ijáíyà
gbani gbani olórun ansáyà
eni tó lemìí mi
móò dé
oníbú ayé…. ò…….
gagun gagun òde òrun o……..
oba tín be níbi gbogbo
àkìjúbà
àpèjúbà
àsàjúbà
osuba re rèé
osuba re rèé
osuba re re…. o
كلمات أغنية عشوائية
- kamz0ner - heavy deal do كلمات أغنية
- halfdan kjerulf - min elskte, jeg er bunden كلمات أغنية
- fabio silva - mesa do canto كلمات أغنية
- chris (deu) - vielleicht كلمات أغنية
- relivia - new (skit) كلمات أغنية
- 高中正義 (masayoshi takanaka) - so excited كلمات أغنية
- king v3gas - tinted windows كلمات أغنية
- yakary & ehro - f4(me) كلمات أغنية
- enemy 906 - guilty كلمات أغنية
- jenni vartiainen - en haluu kuolla tänä yönä كلمات أغنية