
cdq - olowo skit lyrics
Loading...
koma le laleju
koma di ti ara oko o
a tun gbere wa de
awa o wa s’ere ni bi
party qua qua qua quality l’awa se ni bi
a tun ti gbere de
awon to wo fila yellow, to n wo batter blue
to n wa wo jeans purple
to n wa wo shirt ash
e rora ma gbese ati ri yin
sugbon e gbudo kuro nibi te wa yen o
awon ta fi iwe pe ti wole
ah woss wobi
ehn woss wobi
iwo gangan mo n bawi dide o
olowo ti wole
e dide o
olowo ti wole
e dide
olowo ti wole
awon ta fiwe pe ti de o
olowo ti wole
awon ta fiwe pe ti de o
olowo ti wole
eh e lo ma je biscuiti nita o
kawon t’olowo je chicken
olowo ti wole o
e lo je biscuiti ni ta o
kawon olowo je chicken
olowo fe wole
Random Lyrics
- aj simons & umru - hate it, love it lyrics
- petros iakovidis - κοριτσάκι μου (koritsaki mou) lyrics
- özlem taner - gökkuşağı gönder bana lyrics
- pe$o pete - three sword style! lyrics
- troy kingi - leg space lyrics
- pete seeger - bear hunt lyrics
- couch - still feeling you lyrics
- asylum pyre - any hypothesis lyrics
- ivy boy - back to me lyrics
- hailey - love is the answer lyrics