kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

by singers - oluranlowo كلمات الأغنية

Loading...

[verse 1]
angeli bi eniyan
eniyan bi angeli o
oluranlowo kan
t’o nu omije mi nu
t’o gba’so iya lara mi
baba…
ran won simi o
ran won simi o

[verse 2]
awa nwo oju re fun iranlowo
mase je k’awa lo lofo…
kosi eni wa o wa
to lo lowo ofo
mase je kawa lo lofo

[chorus]
eniyan tio waye ti kori iranlowo
owa ye asan ni o…
ran won simi o ran won simi o
alejo oloore tio ran mi lowo
ran won simi o ran won simi o
alejo alaanu tio gbemi dide

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغاني الشهيرة

Loading...