busola martins feat. kentoxygen - arabaribiti (great and mighty god) كلمات الأغنية
arabaribiti…
arabaribiti aribirabata
oba awon oba, mo gbe e yin ga
arabaribiti aribirabata (oba toto bi aro)
eyin loba ologo julo
oh oh oh oh
eyin le ga ju gbogbo aye lo o
eyin le tobi ju t-tobi lo
eyin le fohun ti ase n tele
o wi bee se bee, asoromatase
oba atere kari gbogbo aye
eyin loba ologo julo (araba nla)
arabaribiti aribirabata
(oba to n gbe ‘nu afefe s’ola, o gbe ‘nu adelebo s’ogo o) oba awon oba mo gbe e yin ga
(oba to pe mi to yan mi to fe mi laafetan) arabaribiti aribirabata
(gbigbega ni o, olorun ju awon oke) eyin loba ologo julo
(ariiro ala) arabaribiti aribirabata (o da mi si tiletile…)
(o da mi si tebitara, o da mi si, o pese fun mi) oba awon oba mo gbe e yin ga
(jije mimu n bo si ‘rorun fun mi, t-tobi ni o, olorun ju gbogbo awon oke o) arabaribiti aribirabata
(modupe, modupe modupe) eyin loba ologo julo
you are the king of kings, the lord of lords
the rose of sharon, the rock of ages
mighty man in battle, my god and king
my everything, you are my all in all
there is none like you in all the earth
king of glory i troway salute (iba re oba aterere kari aye eh)
arabaribiti aribirabata
(oba mimo, mimo, mimo, mimo ni yin…) oba awon oba mo gbe e yin ga
(…aimo kan o le sunmo odo yin o baba) arabaribiti aribirabata
(ololufe okan mi) eyin loba ologo julo
kaabiyesi oooo
h-llo eledumare, mo de lati wa f’iyin fun o
lati wa f’ogo fun o ni
iwo loba ti n je emi ni ma se beru
alapa nla ti y’omo re ninu ofin
yaagbo yaaju, oba mi ara m’odu oro
gbingbin-nikin oba awuwo ma see gbe
opa tin-in-rin kan’le o kan orun, olorun oba mi
oba to lojo gbogbo, oba to lo kanrin kese
oba mi akiikitan, oloruko pupo, oloruko repete
a o ma yin o, a o ma gbe o ga, a o ma jo niwaju re
ta la o ba sin bikose iwo oba ti nje emi ni mase beru
t-tobi re ninu orun, oba ogo, oba aseda aye gbogbo
arabaribiti aribirabata (ope, ola, iyin ogo ni f’eledumare loke orun o)
oba awon oba mo gbe e yin ga (a gbe o ga, a se o loba ni)
arabaribiti aribirabata (oro lo wipe; e ma yin oluwa, e f’ope fun oluwa nitori ti o seun, nitori aanu re duro lailai)
eyin loba ologo julo (a yika otun, gbogbo aye se kaabiyesi fun o)
arabaribiti aribirabata (ire la o ma sin, ire la o ma bo…)
oba awon oba mo gbe e yin ga (… a o ni sin orisa, iwo ni, iwo to gbe talaka…)
arabaribiti aribirabata (…dide lati ‘nu erupe wa, o mu joko pel’ awon omo alade)
eyin loba ologo julo (a o ma yin o, a o ma gbe o ga)
eyin loba ooo (eyin loba ologo julo)
eyin loba ologo julo ooo (eyin loba ologo julo)
كلمات أغنية عشوائية
- mostack - the friend كلمات الأغنية
- eidola - loti كلمات الأغنية
- tash (african r&b) - picture me rolling كلمات الأغنية
- braza - selecta كلمات الأغنية
- mario william vitale - a gangster life كلمات الأغنية
- faye webster - say it now كلمات الأغنية
- soijl - weapon of primordial chaos كلمات الأغنية
- black mountain - (over and over) the chain كلمات الأغنية
- la fouine - qds كلمات الأغنية
- ian david - amazing كلمات الأغنية