kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

brymo - tèmi nì tèmi كلمات الأغنية

Loading...

ife mi dariji mi
omode n se mi
afarawe o se temi
ka daduro ni mo wari
moti so tele tele ri
igboro o ma rerin ri
ijakadi lo mu nise
karohunwi o bopo sise

bridge
bi nba fa wa n’ole
bi nba tule wan’loro
bi n duro won ma mere
bi nba sa wa ni mo kere

chorus
aba lo aba bo
b’ohun won ko para won oh
ohun a ni la n nani
temi ni temi

verse 2
awelewa forijimi
mo lakaka kin to de bi
riro mede o se temi
nibi lile la n b’okunrin
ife re sha lo’n duro timi
o dudu, o funfun, o pupa
ife re sha lo’n munu tumi
ninu erun at’ojo at:ilera
bridge
bi nba fa wa n’ole
bi nba tule wan’loro
bi n duro won ma mere
bi nba sa wa ni mo kere

chorus
aba lo aba bo
b’ohun won ko para won oh
ohun a ni la n nani
temi ni temi

outro
aba lo aba bo
temi loje lale eni oh
gbogbo igba ti o ba lo
mo mo pe o pada wa

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغاني الشهيرة

Loading...