bhadboi oml - lagos كلمات الأغنية
always deep inna mi thought, all night long
all i got is hustle o, my saviour, my anchor
melody yìí na my all, i don rise up
i no fit dey vex for my fellow guy wey buy lexus
torí ayé la bá owó
ayé la bá ọmọ
ayé to crucify j, ọmọ ọlọrun
wọn tún pa iró mọ
ayé la bá olá
ayé la bá aya
ṣadé ti fẹ ṣe eléyà pò mó iléyá
ó tún fẹ ra àbáyà
you want to totori me
do you want to be a konkobility?
mi ò dè bá ti eré wá
na lagos we dey, opportunity
mek i totori you
you don’t want to be a konkobility
mi ò dè bá ti eré wá
na lagos we dey, ònà ìlúù mì jìn
ẹwo bàa ṣé n rìn ní ilé
[?][?][?]
igi dá lókè
aféfé ò ní kí ẹyẹ má fò lo
ẹwú n be lódẹ
ọmọ ìyá mí, just show me some love
wèrè po l’èkó
ọmọ ìyá mí, just show me some love
ẹwo bàa ṣé n rìn ní ilé
[?][?][?]
igi dá lókè
aféfé ò ní kí ẹyẹ má fò lo
ẹwú n be lódẹ
ọmọ ìyá mí, just show me some love
wèrè po l’èkó
ọmọ ìyá mí, just show me some love
èrò mi tó n jó, tó n jó lórí omi
èrò mi tó n jó, tó n jó lórí omi
èrò mi tó n jó
èrò mi tó n jó, tó n jó lórí omi
lu pápá, ebi n pa àlejò
onílù mi n bẹ nì ìsàlè odò
olórun ló n bá mi ṣeé, ìgbàyí lolá, ìgbàlódé
èrò mi tó n jó, tó n jó lórí omi
كلمات أغنية عشوائية
- dan lee - wifey كلمات الأغنية
- witches of warboys - the big sad wolf (blood i) كلمات الأغنية
- jihan audy - ojo nguber welase كلمات الأغنية
- nazrief nazri - cinta semalam كلمات الأغنية
- finding favour - what we have is now كلمات الأغنية
- os arrais - jardim (canção de oséias) كلمات الأغنية
- red sauce - every breath you take كلمات الأغنية
- stone sour - the witness trees كلمات الأغنية
- the magnettes - killers in a ghost town كلمات الأغنية
- nikko lowe - apple tree كلمات الأغنية