
beautiful nubia - eleko'dere كلمات أغنية
eleko′dere ṣebo o lo jere
eleko’dere ṣebo o lo jere
eleko′dere ṣebo o lo jere
eleko’dere ṣebo o lo jere
o n ro’ṣọ dudu, o si n ro′ṣo pupa
o n ro′ṣo dudu o si n ro’ṣo funfun
o faimu gbaja o si tun lekenka o
eleko′dere ṣebo o lo jere
eleko’dere ṣebo o lo jere
eleko′dere ṣebo o lo jere
eleko’dere ṣebo o lo jere
eleko′dere ṣebo o lo jere
o n ro’ṣọ dudu, o si n ro’ṣo funfun
o n ro′ṣo dudu o si n ro′ṣo pupa
o faimu gbaja o si tun lekenka o
eleko’dere ṣebo o lo jere
asiko eledumare lo dara
(ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ)
asiko eledumare ni yẹni
(ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ)
ani ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ
(ka f’oun gbogbo s′ọba mimọ lọwọ)
asiko eledumare lo dara
(ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ)
ọrẹ ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ
(ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ)
kii ṣe ti ka joko jẹbẹtẹ
kii ma i ṣe ti ka joko rẹgẹdi
iṣẹ ń bẹ pupọ lati ṣe
kii ma i ṣe ti ka joko bẹbẹrẹ
kii ṣe ti ka joko rọbọtọ
iṣẹ ń bẹ nilẹ lati ṣe
asiko eledumare lo dara
(ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ)
ka f’oun gbogbo s′ọba mimọ lọwọ
(ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ)
asiko eledumare ni yẹni
(ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ)
ani ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ
(ka f′oun gbogbo s’ọba mimọ lọwọ)
asiko ti to ara mi o, asiko ti to
asiko ti to ara mi o, asiko ti to
asiko ti to fun wa o
ara mi, asiko to to fun wa o
ka bo l’oko ẹru (asiko ti to fun wa o)
ka bọ′wu iya sọnu (asiko ti to fun wa o)
b′iṣẹ o ba pẹni o (asiko ti to fun wa o)
ṣeb’ẹnikan i pẹ′ṣẹ (asiko ti to fun wa o)
ka bo l’oko ẹru (asiko ti to fun wa o)
ka bọ′wu iya sọnu (asiko ti to fun wa o)
b’iṣẹ o ba pẹni o (asiko ti to fun wa o)
ṣeb′ẹnikan i pẹ’ṣẹ (asiko ti to fun wa o)
asiko ti to fun wa o
ka bo l’oko ẹru (asiko ti to fun wa o)
ka bọ′wu iya sọnu (asiko ti to fun wa o)
b′iṣẹ o ba pẹni o (asiko ti to fun wa o)
ṣeb’ẹnikan i pẹ′ṣẹ (asiko ti to fun wa o)
ka bo l’oko ẹru (asiko ti to fun wa o)
ka bọ′wu iya sọnu (asiko ti to fun wa o)
b’iṣẹ o ba pẹni o (asiko ti to fun wa o)
ṣeb′ẹnikan i pẹ’ṣẹ (asiko ti to fun wa o)
asiko ti to fun wa (asiko ti to fun wa o)
asiko ti to fun wa …
كلمات أغنية عشوائية
- d&d (jpn) - are you ready? كلمات أغنية
- okkotsuu - забываю (intro) [i forget] كلمات أغنية
- sinéad harnett - unconditional (sonny fodera remix) [mixed] كلمات أغنية
- township - kwame ford كلمات أغنية
- танцы минус (tanzy minus) - тополя пух (poplar fluff) كلمات أغنية
- j álvarez - vivir sin ti (official remix) كلمات أغنية
- scubadiver - electrical كلمات أغنية
- galaxyxy - luv z3 كلمات أغنية
- abey begg - my way كلمات أغنية
- ethna carbery - roddy mccorley كلمات أغنية