
bantu (crew) - ni bo l'anlo كلمات أغنية
[intro: fatai rolling dollar]
a! ọmọ ẹda ẹwaye tan ẹwa nkanju
ọlọhun lo ni gbogbo nkan
ẹma kanju ju kadara a ẹfọkan balẹ
[chorus: oranmiyan]
ni bo lade, i bo la n lo o
ka maşe gbagbe baye şe e n dun fun wa
ka maşe gbagbe ibi ati wa a
[verse 1: wurasamba]
mo ti sọ ọ o, mo ti sọ ifẹ l’eledunmare, mo ti sọ
otitọ l’eledunmare e, mo ti sọ
iye l’eledunmare e, mo ti sọ
imole l’eledunmare o, mo ti sọ
ka mase gbagbe ibi ati wa a o!
ka mase gbagbe ibi ati wa a
[chorus: oranmiyan]
ni bo lade, i bo la n lo o
ka maşe gbagbe baye şe e n dun fun wa
ka maşe gbagbe ibi ati wa a
[verse 2: ade bantu]
brother man stay calm relax and free your mind
reconnect to the source don’t be blind come on
celebrate how far you’ve gone who you are all the mile that you trekked with the sun
ain’t nobody gonna stop your shine caus you’re a buffalo soldier, pyramid builder, afropolitan to the core
show the world out there that you got more
reinvoke the spirit of yester years
gather all the strong ones amongst your peers
it’s a unity thing going on out here
babylon beware jaga jaga clear better move on or f off or shift your gear caus the tables are turning we’re re- aligning educating ourselves with our elders blessings gotta heed the words of our culture’s calling
[chorus: oranmiyan]
ni bo lade, i bo la n lo o
ka maşe gbagbe baye şe e n dun fun wa
ka maşe gbagbe ibi ati wa a
[verse 3; fatai rolling dollar]
ẹda o gba kadara nişe naa sare kiiri
eda o gba kadara nişe naa sare kiiri
wọn gbagbe ayanmọ, wọn gbagbe işẹ oluwa oba
wọn şe wahala lori asan t’ọba ni oşẹ
bẹẹfe bẹẹko, t’oluwa ni o şẹ
ti baba laşẹ, t’oluwa laşẹ o
mo fẹ d’olowo, mo fẹ d’ọlọla t’oluwa laşẹ
mo fẹ k’ọle mo fẹ ra mọto t’oluwa laşẹ
كلمات أغنية عشوائية
- capdown - blood, sweat and fears كلمات أغنية
- capdown - civil disobedients كلمات أغنية
- ft yo gotti future - day 1 (ft. yo gotti) - future كلمات أغنية
- cursive - a distruption in the normal swing of things كلمات أغنية
- capn jazz - precious كلمات أغنية
- dontae peeps - spend the nite كلمات أغنية
- the lylas - headed home كلمات أغنية
- the cooper temple clause - safe enough distance away كلمات أغنية
- bring me the horizon - traitors never play hangman كلمات أغنية
- buddy holly - brown eyed handsome man كلمات أغنية