
bantu (crew) - jagun jagun كلمات أغنية
[chorus]
jagun_jagun ló ń bọ̀
jagun_jagun ló ń bọ̀
jagun_jagun ló ń bọ̀
[verse 1: chant]
olórí_ogun ò gbọdọ̀ kẹ́yìn ogun
ọ̀kan ṣoṣo ẹja tí ń d’abú_omi rú
ọ̀kan ṣoṣo ẹfọ̀n tí ń d’ọ̀dàn rú
ọ̀kan ṣoṣo àjànàkú tí ń m’igbó kìji_kìji
jagun_jagun dé, ọmọ ọba kìí jagun bí ẹrú
òlọ́ṣọmọ́dìí gba ìbọn lọ́wọ́ ọmọ ojo
jagun_jagun, afiwájúgbọta, afẹ̀yìngbọfà
jagun_jagun ò fẹ́rọ̀, alágbára èyàn tí ń fi májèlé ròfọ́
àlùjànú èyàn tí ń fi ọmọ_odó tayín
bó ṣe ń bá ọmọdé ṣe, bẹ́ẹ̀ ló ń bágbà ṣe
kọ̀nàn_kọ̀nàn já tòun tòwú
jagun_aso, ẹkùn ọkọ òkè!
arọnimaja ṣáagun!
ó ṣáagun ṣáagun, ó ṣáagun títí, ohun l’awo alágbàá`a, èyí tí ó fi ta b’aṣeégún lójú
[chorus]
jagun_jagun ló ń bọ̀
jagun_jagun ló ń bọ̀
jagun_jagun ló ń bọ̀
كلمات أغنية عشوائية
- hassaanzic - so what كلمات أغنية
- revivle - youre always on my mind! كلمات أغنية
- sheena easton - what comes naturally (accapella) كلمات أغنية
- louie xo - patience كلمات أغنية
- atrxx - gilded cages come with crowns كلمات أغنية
- lil hope 3x - everyone makes mistakes [bonus track] كلمات أغنية
- zorro - slide on me كلمات أغنية
- nico roberts - people really want to burn كلمات أغنية
- jillian dawn - like my friends do كلمات أغنية
- soil (rock) - halo (re-recorded) كلمات أغنية