kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

apostle ruben agboola jp - wa gbemi ga كلمات الأغنية

Loading...

ọlọ́run àwọn tó ti gá
wá gbé mi náà gá ó
ọlọ́run àwọn tó ti gá
wá gbé mi náà gá ó
lórí ìléde yí àti ní gbọ́gbọ́ àgbáyé
wá gbé mi náà gá ó

ọlọ́run àwọn tó ti gá
wá gbé mi náà gá ó
ọlọ́run àwọn tó ti gá
wá gbé mi náà gá ó
lórí ìléde yí àti ní gbọ́gbọ́ àgbáyé
wá gbé mi náà gá ó
ọgbẹ bàbá jide gá
ni ìgbà ayé tìrẹ
ọgbẹ bàbá lola gá
ni ìgbà ayé tìrẹ
bàbá adeboye ìwọ náà lọ sọ d’eni ńlá
wá gbé mi náà gá ó

ọlọ́run àwọn tó ti gá
wá gbé mi náà gá ó
ọlọ́run àwọn tó ti gá
wá gbé mi náà gá ó
lórí ìléde yí àti ní gbọ́gbọ́ àgbáyé
wá gbé mi náà gá ó

ọgbẹ sólómọ́nì gá ó sọ d’oba
ọlọ́run àgbáyé
àwọn tó ti kọjá lọ
ti ó ron s’àyè
gbọ́gbọ́ wọn ní wọn gbé ilẹ̀ ayé ṣe ìkan tó dára
àsìkò mí nìyí ó bàbá
bá mi ṣe tèmi
ọlọ́run àwọn tó ti gá (ahhh,ahh,ah)
wá gbé mi náà gá
ọlọ́run àwọn tó ti gá
wá gbé mi náà gá ó
lórí ìléde yí àti ní gbọ́gbọ́ àgbáyé
wá gbé mi náà gá ó
ọlọ́run àwọn tó ti gá
wá gbé mi náà gá ó
ọlọ́run àwọn tó ti gá
wá gbé mi náà gá ó
lórí ìléde yí àti ní gbọ́gbọ́ àgbáyé
wá gbé mi náà gá ó

àti lẹ́yìn rẹ elédùmarè
àti lẹ́yìn rẹ ato f’ara ti
àti lẹ́yìn rẹ lọ́ mú ayé mi dúró

àti lẹ́yìn rẹ elédùmarè
àti lẹ́yìn rẹ ato f’ara ti
àti lẹ́yìn rẹ lọ́ mú ayé mi dúró

nínú igi
nínú ìdààmú, ìwọ ló gbé mi dúró
nínú igi
nínú wàhálà, ìwọ lọ fún ní ìsinmi
ọba tí kò fi mi silẹ nígbà kánkán ri
ọlọ́run mí mọ gbé ó ga

àti lẹ́yìn rẹ elédùmarè
àti lẹ́yìn rẹ ato f’ara ti
àti lẹ́yìn rẹ lọ́ mú ayé mi dúró
oti mósè lẹ́yìn
ọtun bà mí ṣé
oti david lẹ́yìn
ọtun ṣé tèmi
bàbá títí ayérayé ún ó má yín ó ọlọ́run mí

àti lẹ́yìn rẹ elédùmarè
àti lẹ́yìn rẹ ato f’ara ti
àti lẹ́yìn rẹ lọ́ mú ayé mi dúró
àti lẹ́yìn rẹ elédùmarè
àti lẹ́yìn rẹ ato f’ara ti
àti lẹ́yìn rẹ lọ́ mú ayé mi dúró

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغاني الشهيرة

Loading...