
annex vodka - jeje كلمات الأغنية
yea;
vodka
its your boy
bridge:
daddy mi se jeje;
lomu ki mummy m¡ gba jeje;
won bi mi saye; won ko mi;
won ni kin se jeje o
ch0rus:
oya se jeje; oo
moni se jeje oo
oya se jeje oo
aiye gba jeje oo
verse 1:
oya se jeje;
awelewa; dakun se jeje;
jhur woju mi; iwo mofefe;
tin ba be e; ni kogbebe o;
mi o sho tele;
o n woju mi bi oko tele;
kilo wa sele tofi mile;
if you refuse 2 femi moma lele o;
owa ni kin nwara aston martin;
ni reti pe mofe gba salary;
givenchy, ferrari;
that reminds me; which time we go marry o;
bridge:
daddy mi se jeje;
lomu ki mummy mi gba jeje;
won bi mi saye; won ko mi;
won ni ki nse jeje o;
chorus:
oya se jeje; oo
moni se jeje; oo
oya se jeje; oo
aiye gba jeje; oo
verse 2
moni se jeje;
o woju mi, oni m0fete;
dakun dabo kotu se jeje;
aye ti lewu ko se jeje o;
o mo mi loju;
mo shewo si; oni kin gboju;
ife yi ma ti npa mi lekun;
omije ojumi gan ti fekun;
lose ni kin lo ra buggati;
nitoripe mofe ma ba tally;
hustle yi ga; ki nto wo zannoti;
dreamchaser ni mi; mi o ki n sho mo mummy;
bridge:
daddy mi se jeje;
lomu ki mummy mi gba jeje;
won bi mi saye; won ko mi;
won ni ki nse jeje o;
chorus:
oya se jeje; oo
moni se jeje; oo
oya se jeje; oo
aiye gba jeje; oo
verse 3:
ma’ami jeje;
won w0ju mi, vodka jeje;
odo ju mi, odoju e;
tin ba ti nrin; ki n te jeje o;
brother jeje;
olenu gan bobo se jeje;
jhur shey n0rmal; aiye ti fele;
aiye ti lewu ogba jeje; o
sister jeje;
orekelewa mi abike;
oju ti ran; jhur se jeje;
aiye ti lewu; se jeje o;
chorus
beats fade out
كلمات أغنية عشوائية
- 5051 - туристическая (turisticheskaya) كلمات الأغنية
- daniel tanghal - molly كلمات الأغنية
- of the wand & the moon - fall from view كلمات الأغنية
- pez errante - ciegos كلمات الأغنية
- cīgu pārdevējs - automātisks كلمات الأغنية
- xxxvrny - show كلمات الأغنية
- milonair & capital bra - bmdbm كلمات الأغنية
- desxlate - хуже (worse) كلمات الأغنية
- alcove dream - mr. brown كلمات الأغنية
- ksonrap - safari كلمات الأغنية