
angélique kidjo - aisha lyrics
Loading...
aisha, omidan ọla, ma sunkun
aye rẹ, o wa niwaju ẹ
onikaluku wa, gbogbo wa ni ododo
aisha, wahala ni aye
gbadun ni aye, ọjọjumọ ni o
oju ọjọ k’a maa dupẹ o
ọmọde maa sunkun, aye yii o daa
fi ogun silẹ, ma lọ
aisha, omidan ọla, ma sunkun
aye rẹ, o wa niwaju ẹ, ọmọde
onikaluku wa ma jẹ ẹjọ ninu aye
onikaluku yoo duro fun ẹsan ọmọ
aisha, ma lọ
aisha, omidan ọla
ọmọde, wa k’a lọ
omọde, onikaluku wa l’ahun wa ododo
[?]
aisha
aisha
Random Lyrics
- leo hainer - 100 times lyrics
- bart baker - kimye lyrics
- robson & jerome - i'll come running back to you lyrics
- nikki flores - after all lyrics
- dozer mc - trap legado lyrics
- houlis & fy - hoodwalk lyrics
- lucybell - por amor lyrics
- 83 babies - okay lyrics
- hiroyuki sawano - grenzlinie lyrics
- emily brimlow - dust on the ground lyrics