kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

agaga feat. qdot - jaa كلمات الأغنية

Loading...

sebi ó ni kosi ibiti olorun osi
ankara moni gucci ni osi
atm wa owo ni osi o
majè kómó ólórun mi kusi inu osi o
toba jè awón tobi mi lofori pe egun
laye ójó un ni… moja
bojè mamami… moja
bojè babami… moja
bojè awón to sunmó mi. moja
jakiri jaa jaa jaa
bojè iyawo mi… moja
abómo ti mo nba sun
ibitoti gbebi mi. moja
tabi omi tofi wé mi ni… moja
jakiri jaa jaa jaa
babami ti se won ri se
iyami ti se won ri se
awón ebi mi se won ri se
lasiko temi jè n ri se
to holy ghost mi ba ti fire tan
owo ni ko bami wire na
to owo ba wole komasi agbana
to ogo mi ba de ko ma di taana
imólè mi se èru ba okunkun wón
kalaba fè ojuju wón
toba jè awón tobi mi lofori pe egun
laye ójó un ni… moja
bojè mamami… moja
bojè babami… moja
bojè awón to sunmó mi. moja
jakiri jaa jaa jaa
bojè iyawo mi… moja
abómo ti mo nba sun
ibitoti gbebi mi. moja
tabi omi tofi wé mi ni… moja
jakiri jaa jaa jaa
pac_p_nt ti o ni visa id card ni. ólórun
ówó ti o ka owo ri handicap ni. ólórun o
bèlé o lómó ani bèlé o lómó
bet9ja la nri jè,
bet9ja ta n ri jè gan
wón pada jèwa
saraabulihaimó
ani bèlé o lómó
bet9ja la nri jè,
bet9ja ta n ri jè gan
wón pada jèwa
saraabulihaimó, elofirija eloserini
eliferalabeilu loalerimó
baba se iyanu laye mi
sebi ó ni kosi ibiti olorun osi
ankara moni gucci ni osi
atm wa owo ni osi o
majè kómó ólórun mi kusi inu osi o
toba jè awón tobi mi lofori pe egun
laye ójó un ni… moja
bojè mamami… moja
bojè babami… moja
bojè awón to sunmó mi. moja
jakiri jaa jaa jaa
bojè iyawo mi… moja
abómo ti mo nba sun
ibitoti gbebi mi. moja
tabi omi tofi wé mi ni… moja
jakiri jaa jaa jaa

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغاني الشهيرة

Loading...