kalimah.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

adekunle gold - temptation كلمات الأغنية

Loading...

e wo mi mo ti ko si trouble
o my god, see me see gobe, e gbe mí èyí ma le
orí mi soldier, he go to war e don tẹ

he go for long, family e wọn tí give up
ìyàwó ọrẹ mi báde, ó ní ká máa ṣe wọlé wode
wípé ká má kolabo papọ
i tell her say hie no dey proper, she tell me say hie no matter, kosi ohun tútù lábé ọrùn o
mo ní ra, mo ní ose
má kò bá mi ò, don’t implicate mi jor woo
mo ní rárá (mo ní rara), mo ní mi ò ṣe oo
má kò bá mi, mi ò ní dálèe ore
damilola is a hot girl, kama pa ro she make sense
i no go lie i think ham o
orí mi soldier he dirty gan, he no dey smile he no dey laugh
to bá lọ mo, i don die
ìyàwó mi tún de, she say make we dey friend each other
wípé ká má kolabo papọ
i tell her say hie no dey proper, she tell me say hie no matter, kosi ohun tútù lábé ọrùn o
mo ní ra, mo ní ose
má kò bá mi ò, don’t implicate mi jor woo
mo ní rárá (mo ní rara), mo ní mi ò ṣe oo
má kò bá mi, mi ò ní dálèe ore
this na temptation, wey dey lead to confusion
few months later, ore de
e jor ẹ kì mi kú ewu mo bo nínú wàhálà
ọrẹ mi soldier he come back inu mi dùn ayo mi kun wípé mo bo nínú wàhálà
ìyàwó mi tún de, ó ní ká má shoki sobonlo
wípé ká má kolabo papọ
i tell her say hie no dey proper, she tell me say hie no matter, shey bí ayé ṣe irú e
mo ní ra, mo ní ose
má kò bá mi ò, don’t implicate mi jor woo
mo ní rárá (mo ní rara), mo ní mi ò ṣe oo
má kò bá mi, mi ò ní dálèe ore

كلمات أغنية عشوائية

كلمات الأغاني الشهيرة

Loading...