
9ice - ojo lyrics
ojo to ru si ewuro
lo ro si ireke
se bi saati rahmoni baba ba wa se
asese o la bijun
a tun se ni ma le
koriko terin ba te ko ma tun dide
oke agba ni mo gun yi o x4
e ma jen jaabo
oke agba ni mo gun yi o x3
e ma jen jaabo
omo to ba sisi dede
o ye ko ni igbadun
adun obe o nbe ninu shasun
this one na the part 1
you never see the part 2
we are relevant just like your tattoo
won ni mo saare wa mo saare
mo de tun gbe eni wa, mo gbe eni wa
mo de pe shalewa, pe shalеwa
ko de lo gbe o ti wa, lo gbo ti wa eh
ojo to ru si еwuro
lo ro si ireke
se bi saati rahmoni baba n ba wa se
asese o la bijun
a tun se ni ma le
koriko terin ba te ko ma tun dide
oke agba ni mo gun yi o x4
e ma jen jaabo
oke agba ni mo gun yi o x3
e ma jen jaabo
ise leye ile se ko to fin se ise kole
ise looka baba se to fi p__poro sole
ise nla ni mo se kin to pa owo mi wa le
ma je aye ori mi, ma fin amebo mi sole
won ni mo saare wa mo saare
mo de tun gbe eni wa, mo gbe eni wa
mo de pe shalewa, pe shalewa
ko de lo gbe o ti wa, lo gbo ti wa eh
ojo to ru si ewuro
lo ro si ireke
se bi saati rahmoni baba n ba wa se
asese o la bi jun
a tun se ni ma le
koriko to terin ba te ko ma tun dide
oke agba ni mo gun yi o x4
e ma jen jaabo
oke agba ni mo gun yi o x3
e ma jen jaabo
oke oke oke
e ma jen jaabo
beat, chris, underscore
Random Lyrics
- old crow medicine show - caroline lyrics
- fatima mansions - viva dead ponies lyrics
- gamma ray - chasing shadows lyrics
- gamma ray - who do you think you are lyrics
- daemonlord - the decline lyrics
- wailers - small axe lyrics
- kat dahlia - mirror lyrics
- xtc - melt the guns lyrics
- pansy division - expiration date lyrics
- meredith andrews - open up the heavens lyrics